Bitcoin

Àdàkọ:Special characters

Bitcoin
Prevailing bitcoin logo
Prevailing bitcoin logo
Denominations
Pluralbitcoins
Symbol[lower-alpha 1]
Ticker symbolBTC, XBT[lower-alpha 2]
Precision10−8
Subunits
11000millibitcoin
1100000000satoshi[2]
Development
Original author(s)Satoshi Nakamoto
White paper"Bitcoin: A Peer-to-Peer Electronic Cash System"
Implementation(s)Bitcoin Core
Initial release0.1.0 / 9 Oṣù Kínní 2009; ọdún 15 sẹ́yìn (2009-01-09)
Latest release0.18.0 / 2 Oṣù Kàrún 2019; ọdún 4 sẹ́yìn (2019-05-02)[3]
Development statusActive
Websitebitcoin.org
Ledger
Ledger start3 Oṣù Kínní 2009; ọdún 15 sẹ́yìn (2009-01-03)
Timestamping schemeProof-of-work (partial hash inversion)
Hash functionSHA-256
Issuance scheduleDecentralized (block reward)
Initially ₿50 per block, halved every 210,000 blocks[7][8]
Block reward₿12.5[lower-alpha 3]
Block time10 minutes
Block explorerbitaps.com/
Circulating supply₿17,754,100 (títí di 11 Oṣù Kẹfà 2019 (2019 -06-11))
Supply limit₿21,000,000[4][lower-alpha 4]

Bitcoin (, Bítkọìn ní gbólóhùn Yorùbá) jẹ́ owóníná onísíṣeàmìkíkọpamọ irú owó kíkà orí kọ̀mpútà kan. O jẹ́ owóníná orí kọ̀mpútà aláìníolùgba-àrin tí kò ní bánkì agba-àrin rárá tí ẹníkan le fún ẹlòmíràn lórí ẹ̀rọ kọ̀mpútà álásopọ̀ ọ̀rẹ́sọ́rẹ̀ẹ́ láì sí ẹnìkankan ní àrin wọn.[7]

Àwọn kọ̀mpútà alásopọ̀ nodes ló ún ṣe ìjẹ́ẹ̀rí àwọn ìdúnàádúrà tó únṣẹlẹ̀ pẹ̀lú ìṣeàmìkíkọpamọ́ tí wọ́n jẹ́ kíkọ sínú ìwé-àkọọ́lẹ̀ pípínkiri tó hàn sí gbogbo ènìyàn tí à ún pè ní blockchain. Bitcoin jẹ́ dídá sílẹ̀ látọwọ́ ẹnìkan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn ẹníkan tí orúkọ wọn únjẹ́ Satoshi Nakamoto[9] tó sì jẹ́ fífi s'óde gẹ́gẹ́ bíi ìlànà ìṣiṣé kọ̀mpútà atúdìísílẹ̀ ní ọdún 2009.[10] Àwọn bitcoin únjẹ́ dídá gẹ́gẹ́ bi ẹ̀san fún ìgbéṣẹ̀ kọ̀mpútà tí à ùn pè ní mining. Wọ́n ṣe é fi ṣe pasípàrọ̀ fún àwọn owóníná míràn, èso-iṣé àti ìránṣe-iṣẹ́.[11]



Itokasi

Àdàkọ:BitcoinÀdàkọ:Cryptocurrencies