Jump to content

Ìmọ̀ àjàkálẹ̀-àrùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìmọ̀ àjàkálẹ̀-àrùn ni ẹ̀kọ́ àti ọ̀nà ìgbékalẹ̀ àti ìgbéyẹ̀wò bí àrùn ṣe ń tàn kálẹ̀ láàrín àwọn ènìyàn. Ó tún jẹ́ ọ̀nà (ìwádìí àrùn), àti ohun ń fa àjàkálẹ̀ àrùn.Ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ilé-iṣẹ́ ìjọba tó ń mójútó ìbẹ́sílẹ̀ àjákálẹ̀-àrùn ni Nigeria Centre for Disease Control.

Itokasiàtúnṣe àmìọ̀rọ̀

🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Pàtàkì:SearchEre idarayaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáIṣẹ́ Àgbẹ̀Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀṣà YorùbáÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÒgún LákáayéWikipedia:Nípa WikipediaWikipediaOwe YorubaAkanlo-edeỌrọ orúkọOrúkọ YorùbáWikipedia:Èbúté ÀwùjọHóséà Ayoola AgboolaÈdè YorùbáPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunWikipedia:Abẹ́ igiÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Wikipedia:Àwọn àyọkà kúkúrúFáwẹ̀lì YorùbáÒrò àyálò YorùbáGbólóhùn YorùbáÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáAṣọHerbert MacaulayMọ́remí ÁjàṣoroṢàngóOmiEwìItan Ijapa ati AjaÀrokòAustrálíàIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Yewa