Aacocrinus

Aacocrinus, tí wọ́n tún mọ̀ sí ìyẹ́ ìràwọ̀, jẹ́ òdòdó òkun tí a kò rí mọ́ lati ẹbí Actinocrinitidae (tàbí Patelliocrinidae).[4][5][6][7][8][9][10][11][12][13]  Wọ́n ti fi hàn wípé ó tòrò mọ́ nkan elẹ́mí kan tí ó maa ń jẹ àwọn nkan ẹlẹ́mí tí ó bá kọjá láì rí wọn. Mg calcite, wà lára rẹ̀, ó sì ń gbé ní òkè epifauna.[14][15][16]

Aacocrinus
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ìpín:
Echinodermata
Ẹgbẹ́:
Crinoidea
Ìtò:
Monobathrida[1]
Ìdílé:
Actinocrinitidae;[2] Patelliocrinidae[1]
Ìbátan:
Aacocrinus

Bowsher, 1955[3]
Species

See text

Lọ́wọ́lọ́wọ́, ẹ̀yà mẹ́rìndínlógún ni ó wà nínú ìdílé yìí:


  • Aacocrinus acylus (Webster & Jell 1999)[17][18]
  • Aacocrinus algeriaensis (Webster, Maples, Sevastopulo, Frest & Waters 2004)[19][20]
  • Aacocrinus boonensis [21]
  • Aacocrinus chouteauensis[22]
  • Aacocrinus enigmaticus (Webster & Lane 1987)[23]
  • Aacocrinus milleri[24]
  • Aacocrinus nododorsatus (Bowsher 1955)[25][26]
  • Aacocrinus protuberoarmatus (Missouri)[27]
  • Aacocrinus sampsoni[28]
  • Aacocrinus senectus[29]
  • Aacocrinus spinosulus[30]
  • Aacocrinus spinulosus[31]
  • Aacocrinus tetradactylus (Missouri)[32]
  • Aacocrinus triarmatus[33]

Àwọn ìtọ́kasí