Aaglacrinus

Aaglacrinus jẹ́ ẹ̀yà crinoidea ní ìhà Cladia tí a kò rí mọ́.[6][7][8][9][10] Wọ́n ti gbèrò wípé kò lè rín (tòrò) nkan elẹ́mí kan tí ó maa ń jẹ àwọn nkan ẹlẹ́mí tí ó bá kọjá, tí Magnesium calcite, wà lára ibi tí ó le lára rẹ̀.[11][12]

Aaglacrinus
Temporal range: 359.2–299.0 Ma Carboniferous[1]
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Echinodermata
Ẹgbẹ́:
Crinoidea
Ìtò:
Cladida
Ìdílé:
Dendrocrinidae
Ìbátan:
Aaglacrinus

G. D. Webster, 1981[2][3]
Species

See text

Synonyms

Aaglaocrinus[4][5]

Àwọn ẹ̀yà

Lọ́wọ́lọ́wọ́, ẹ̀yà méjì ni ó wà nínú ìdílé yìí, àwọn méjèèjì wà lábẹ́ orúkọ Aaglaocrinus:

  • Aaglaocrinus bowsheri (Webster & Kues, 2006)[13][14]
  • Aaglaocrinus sphaeri (Strimple 1949)[15][16][17]

Ìwé àkàsíwájú si

  • [1]
  • [2][Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  • [3] Archived 2013-01-05 at archive.ph Error: unknown archive URL

Àwọn ìtọ́kasí