Aberdeen

Ìlú ńlá kan nìyí ní ìlà-oòrùn àríwá ilẹ̀ Scotland. Ara Káúntì (County) Aberdeenshire ni ó wà tẹ́lẹ̀. Láti oṣù kárùn-ún ọdún 1975 ni ó ti di ara Grampian. Wọ́n máa ń pe Aberdeen ní ‘granite city’. Ó ní Yunifásítì kan tí wọ́n dá sílẹ̀ ní 1494. Aberdeen Angus ni wọn máa ń pe orúkọ àgùntàn kan tí ó gbajúmọ̀ ní Aberdeen. Àwọn ará ìlú Aberdeen ni wọ́n ń pè ní Aberdonian.

Aberdeen

Aiberdeen

Obar Dheathain
Marischal College from Broadhill
Marischal College from Broadhill
Nickname(s): 
Granite City, Oil Capital of Europe, Silver City
Population
 • TotalUrban area -

184,788[1] (2,001 census)
est. 192,080[2] (2,006)
inc. Cove Bay & Dyce
Local Authority -

est. 202,370[3] (2,005)
 • Density1,089/km2 (2,819/sq mi)
Websiteaberdeencity.gov.uk