Bọ́ọ̀lù-alápẹ̀rẹ̀

Bọ́ọ̀lù-alápẹ̀rẹ̀ tabi básíkẹ́tbọlù (basketball) ni ere-idaraya ẹlẹgbẹ́, ti ero ibe ni lati ju boolu sinu awon alapere gegebi awon ilana re se la sile. O je ere-idaraya egbe agbaboolu pelu awom agbaboolu marun ninu egbe kookan lori papa to ni opo awon alapere. Bọ́ọ̀lù-alápẹ̀rẹ̀ gbajumo kakiri aye.[1]

Bọ́ọ̀lù-alápẹ̀rẹ̀
Michael Jordan goes for a slam dunk at the old Boston Garden
Highest governing bodyFIBA
First played1891, Springfield, Massachusetts, U.S.
Characteristics
ContactContact
Team members10-20 (5 on court)
Mixed genderSingle
CategorizationIndoor (mainly) or Outdoor (Streetball)
EquipmentBasketball
OlympicDemonstrated in the 1904 and 1924 Summer Olympics
Part of the Summer Olympic programme since 1936



Itokasi