Biochemistry
Biochemistry, nígbàmíràn wọ́n máa ń pèé ní biological chemistry, jẹ́ ìmọ̀ ìlànà kẹ́míkà àgọ́ ara àtí ìbáṣepọ̀ wọn pẹ̀lú ohun ẹlẹmí.[1] Nípa ṣíṣe àkóso lílọ-bíbọ̀ iṣẹ́ lágọ́ ara nípasẹ̀ ìtalólobo ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà àti lílọ-bíbọ̀ agbára kẹ́míkà làtàrí gbogbo ìbáṣepọ̀ kẹ́míka nínú ara, ìlànà kẹ́míkà nínú ara yìí ní ó máa ń ṣe ìmúgbòòrò bí ara ṣe ń ṣiṣẹ́.Ní bíi ogún ọrundún sẹ́yìn, biochemistry ti ṣe àṣeyọrí lórí bí a ṣe lè ṣàlàyé lórí ìlànà ìgbéayé tí ó ni ṣe pẹ̀lú ìmọ ohun ẹlẹ́mí làti ìmọ̀ ewéko sí ìmọ̀ ìlera, sí ìmọ̀ ìṣiṣẹ́àbínimọ́ ní wọ́n ní ṣe pẹ̀lú ìwádí ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà lágọ́ ara.[2] Loní, ìdojúkọ ìwádí ní biochemistry dá lórí òye bí biological molecules ṣe ń f ìlànà tó ń ṣẹlẹ̀ nínú àwọn ètò ẹ̀yà ara.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN