Blood Sisters (fíìmù 2022)

Blood Sisters je ere Naijiria ti Netflix gbe jade ni odun 2022[1] Ere yii je akoko ere Naijiria ti yo wo Netflix Original series, awon agba osere ibe ni[2] Ini Dima-Okojie ati Nancy Isime , peelu Ramsey Nouah, Kate Henshaw, Wale Ojo, Kehinde Bankole, Deyemi Okanlawon, Gabriel Afolayan, Tope Tedela peelu awon elere miiran.[3] Awon apa meerin ere na jaade ni ojo kaarun osu kaarun odun 2022, eyi si je ibeere ifowosowopo Netflix ati Mo Abudu nipase ilese ere re , Ebonylife TV.[4] Biyi Bandele ati Kenneth Gyang ni oludaari fíìmù Blood sisters.[5][6]

Blood Sisters
Fáìlì:Blood Sisters (2022 series) poster.png
GenreNigerian Crime Thriller
Directed by
Starring
Music byKulanen Ikyo
Country of originNigeria
Original language(s)Geesi
No. of seasonsokan
No. of episodesmeerin
Production
Producer(s)Mo Abudu
Running timeaadota iseju
Release
Original networkNetflix
Original release5 Oṣù Kàrún 2022 (2022-05-05)

Awon Osere

Àwọn ìtọ́kasí