Cola urceolata

Taxonomy not available for Cola; please create it automated assistant

Cola urceolata, ti a tun mo sí bemange, bokosa, eboli, egwasa, ikaie, lekukumu, lungandu, lusakani, matadohohu, nesunguna, ngbilimo, ngono, ati zimonziele, je alododo shrubu ni idile Malvaceae.Specific epithet(urceolata) wa lati  Latin urceus (= pitcher, jug) ati wipe o tun mo sí "urn-shaped"

Cola urceolata
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Template:Taxonomy/ColaC. urceolata
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/ColaCola urceolata
K.Schum. (1900)
Synonyms
  • Cola longifolia De Wild.
  • Cola nalaensis De Wild.
  • Cola nalaensis subsp. variifolia De Wild.
  • Cola yambuyaensis De Wild.

Ìtànkálẹ̀

Cola urceolata wọ́pọ̀ ní Central Africa, láti apá Gúúsù mọ́ Ìlà-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà lọ sí apá Gúúsù ilè Kongo Central ní Democratic Republic of the Congo, àti ní apá Àríwá mọ́ Ìlà-oòrùn sí apá Gúúsù mọ́ Ìlà-oòrùn Central African Republic.[1]

Àpèjúwe

Cola urceolata jẹ́ igi kékeré tó ga tó 3 meters (9.8 feet) ní ìwọ̀n gíga.[2] Ewé gíríìnì rẹ̀ àti òdòdò funfun rẹ̀ jẹ́ aláwé m ẹ́ta.[1] Èsò rẹ̀ jọ ata, ó sì máa ń pupa tó bá pọ́n, àmọ́ tí kò báì pọ́n, àwọ̀ rẹ̀ máa jọ àwọ̀ ewé. Ẹnu rẹ̀ rí ṣonṣo, èso, kóró, òdòdó àti ewé rẹ̀ ṣe é jẹ.[2]

Ìwúlò

Èso àti àwọn ẹ̀yà rẹ̀ ṣe é jẹ ní tu htù tàbí ní sísè.[2]

Àwọn ìtọ́kasí