Emperor Shaka the Great
Emperor Shaka the Great jẹ́ ewì tí ó dá lórí àṣà Zulu, wọ́n ko ewì náà ní Zulu kí akéwì kan ní Mazisi Kunene tó tun kọ. Ewì náà sọ nípa ayé Shaka Zulu, àti nípa àwọn ìṣe rẹ̀ nígbà tí ó jẹ́ ọba àwọn ènìyàn Zulu, ìtẹ̀síwájú dé bá ìlú Zulu àti àwọn ohun èlò ogún tí àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ń lò.
Fáìlì:Emperor Shaka the Great.jpg | |
Olùkọ̀wé | Mazisi Kunene |
---|---|
Cover artist | Ingrid Crewdson |
Country | South Africa |
Language | English |
Series | Heinemann African Writers Series |
Genre | Zulu heroic epic poetry |
Publication date | 1979 |
Pages | xxxvi + 438 |
Ìtàn àtenudẹ́nu
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn ará Zulu tí ma ń kó ewì àtenudẹ́nu láti àtayédáyé, wọn o sọ púpò nípa àwọn ìṣe Zulu titi di ìgbà ìjọba Shaka.[1] Ewì yí sọ nípa àwọn ìṣe ìjọba àti ìtàn Shaka.[2] Gẹ́gẹ́ bi àṣà àti ìgbàgbọ́ Zulu, àwọn akéwì (izimbongi) jẹ́ àwọn tí ó ń sọ nípa ìgbàgbọ́ àti àṣeyọrí àwọn ará Zulu.[3]
Àwọn tí ó wà nínú ewì náà
- Shaka Zulu
- Senzangakhona – Bàbá Shaka àti ọba Zulu
- Nandi – Ìyá Zulu
- Mkhabayi – Àùntí Shaka
Àwọn Ìtọ́kasí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Pàtàkì:SearchEre idarayaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáIṣẹ́ Àgbẹ̀Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀṣà YorùbáÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÒgún LákáayéWikipedia:Nípa WikipediaWikipediaOwe YorubaAkanlo-edeỌrọ orúkọOrúkọ YorùbáWikipedia:Èbúté ÀwùjọHóséà Ayoola AgboolaÈdè YorùbáPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunWikipedia:Abẹ́ igiÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Wikipedia:Àwọn àyọkà kúkúrúFáwẹ̀lì YorùbáÒrò àyálò YorùbáGbólóhùn YorùbáÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáAṣọHerbert MacaulayMọ́remí ÁjàṣoroṢàngóOmiEwìItan Ijapa ati AjaÀrokòAustrálíàIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Yewa