Erin

Erin (tàbí àjànàkú) jẹ́ ẹranko afọ́mọlọ́mú orí ilẹ̀ títóbi tí a kà sí ìbátan méjì ti ẹbí Elephantidae (Ẹ̀dá-àjànàkú): Elephas àti Loxodonta. Irú erin mẹ́ta ló yè lóde òní: àjànàkú ọlọ́dàn Áfíríkà, àjànàkú onígbó Áfíríkà, àti àjànàkú Ásíà (tí a tún pè ní àjànàkú Íńdíà). Gbogbo irú erin yòókù ti kú run, àwọn kan kú run ní sànmánì olómidídì, ṣùgbọ́n, ó ṣeé ṣe pé àwọn aràrá erin abirun-lára kan yè títí dé nǹkan bíi 2,000 BCE.[1]

Àjànàkú ọlọ́dàn Áfíríkà
Egungun àjànàkú Áfíríkà
Fáìlì:African-Asian-Elephants.png
Asian (Elephas maximus) and African (Loxodonta) elephants.



Ìtọ́kasí