Garcinia humilis
"Achacha" túndarí síbí yìí. Fún the town in Algeria, ẹ wo Achacha, Algeria.
Taxonomy not available for Garcinia; please create it automated assistantGarcinia humilis, ti a tun mo sí achachairú or achacha, je eso igi ti o kere ti o tun tan mo mangosteen. O maan Wu ni apa southern Amazon basin ni aarin agbègbè Bolivia, sugbon ni enu ijo meta yii,a gbin ni rẹpẹtẹ fun tita ni Burdekin, Australia. Eso yi se ipo keta ni ọdún 2012 ni àwardi Fruit Logistica Innovation Awards ti won se ni Berlin.[1]
Garcinia humilis | |
---|---|
![]() | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Irú: | Template:Taxonomy/GarciniaG. humilis |
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Template:Taxonomy/GarciniaGarcinia humilis (Vahl) C.D.Adams |
Appearance
Achacha je eso ti o dara lati wo loju,awo rè sí da gidi. Irisi re dàbí ti eyin,o sì to centimeter mefa sí mẹrin ni diameter. O ni awo pupa mọ osan ti o ba pọn. Eso kaffee ti o se pataki ni,sugbon eso yìí lè ní ju irúgbìn eyo kan lo.
Awọn Atokasi
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìẸ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1956Pàtàkì:SearchWikipediaÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáEre idarayaPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáf9qfoỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)ÀrokòWikipedia:Èbúté ÀwùjọṢàngóFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgÈdè YorùbáÒgún LákáayéIṣẹ́ Àgbẹ̀Wikipedia:Abẹ́ igiDavid EjoorWikipedia:Nípa WikipediaCristiano RonaldoÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíÀṣà YorùbáMediaWikiFinidi GeorgeWikipedia:Ìṣẹ̀lẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́Owe YorubaFáwẹ̀lì YorùbáWikipedia:Àyọkà pàtàkìÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáMagnesiumÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Wikipedia:NípaGbólóhùn YorùbáẸ̀ka:Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́Akanlo-edeGírámà YorùbáOsinlokun