George Maxwell Richards
George Maxwell Richards, TC, CM (born 1931) ni Aare ikerin orile-ede Trinidad and Tobago. Onimo iseero kemika, Richards lo tije Oluko Agba Ogba St. Augustine ti Yunifasiti West Indies ni Trinidad ni 1996. Teletele o tun ti sise fun Shell Trinidad Ltd. ko to dipe o bo si Yunifasiti West Indies ni 1965. O di Aare ni March 17, 2003 fun igba odun marun. Richards ni Olori Orile-ede akoko ni Anglophone Caribbean to je Amerindian.
George Maxwell Richards TC CM | |
---|---|
Fáìlì:GeorgeMaxwellRichards.jpg | |
Aare ile Trinidad ati Tobago | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 17 March 2003 | |
Alákóso Àgbà | Patrick Manning Kamla Persad-Bissessar |
Asíwájú | Arthur Robinson |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1931 (ọmọ ọdún 92–93) San Fernando, Trinidad and Tobago |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Jean Ramjohn-Richards |
Alma mater | Queen's Royal College University of Manchester Institute of Science and Technology Pembroke College, Cambridge |
Profession | Chemical Engineer Chancellor |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN