Olórí ìjọba

(Àtúnjúwe láti Head of government)

Olórí ìjọba ni osise agba tin o je apase ijoba[1], to solori ipade kabineeti. Ninu ilana ileasofin, olori ijoba ni a mo bi Alakoso Agba, tabi Aare Ijoba, Asiwaju, ati bee bee lo.[2] Ni ilana orile-ede olominira yiyan Aare tabi awon Oba alase, olori ijoba le je enikan naa bi olori orile-ede, ti an pe ni Aare tabi Oba.[3]


Awon Itokasi