Hope Waddell Training Institute

Hope Waddell Training Institution (HOWAD) jẹ́ ilé-ìwé ẹ̀kọ́ṣẹ́ tí ó fìkàlẹ̀ sí ìlú Calabar, ní Ìpínlẹ̀ Cross River, lórílẹ̀-èdè Nigeria. Àwọn àlùfáà ìjọ kìrìsìtẹ́nì ti United Presbyterian Church of Scotland ni wọ́n dá a sílẹ̀ lọ́dún 1895, tí wọ́n sì só lorúkọ àlùfáà ìjọ náà nígbà náà Hope Masterton Waddell.[1]

Hope Waddell Training Institution
Fáìlì:Hope Wadell Logo.jpg
MottoIn Spe Gloria Dei
("In hope of the glory of God")
Established1895
TypeSecondary
LocationCalabar, Cross River State, Nigeria

Àwọn ọ̀gá-àgbà ilé-ìwé náà láti ìbẹ̀rẹ̀

Àwọn wọ̀nyí ni ọ̀gá-àgbà ilé-ìwé náà títí di ọdún 1960 síwáju:[2]

ọ̀gá-àgbà ilé-ìwéẸ̀yàọdún
W.R. Thompsonọmọ orílè-èdè Scotland1895 - 1902
James Lukeọmọ orílè-èdè Scotland1902 - 07
J.K. Macgregorọmọ orílè-èdè Scotland1907 - 43
E. B. Jonesọmọ orílè-èdè Scotland1943 - 45
N. C. Macraeọmọ orílè-èdè Scotland1945 - 52
J. A. T. Beattieọmọ orílè-èdè Scotland1952 - 57
Sir Dr. Francis Akanu Ibiamọmọ Ìgbò1957 - 60
B. E. Okonọmọ Efik1960 - 74

Àwọn Ìtọ́kasí