Ikeja

agbegbe ijoba ibile Nigeria

Ikeja je oluilu ipinle Eko ni guusu iwo oorun Naijiria . Awon olugbe rẹ, ni asiko ikaniyan odun 2006 je 313,196.

Ikeja
Municipality
Ikeja Local Government Area
Ikeja shown within the State of Lagos
Ikeja shown within the State of Lagos
Ikeja is located in Nigeria
Ikeja
Ikeja
Location in Nigeria
Coordinates: 6°36′N 3°21′E / 6.60°N 3.35°E / 6.60; 3.35 3°21′E / 6.60°N 3.35°E / 6.60; 3.35
Country Nigeria
StateLagos State
LGA(s)Ikeja
Area
 • Total49.92 km2 (19.27 sq mi)
 • Land49.92 km2 (19.27 sq mi)
Elevation
39 m (128 ft)
Population
 (2006 census)[1]
 • Total313,196
 • Density6,300/km2 (16,000/sq mi)
Time zoneUTC+1 (WAT)
ClimateAw

Papa ọkọ ofurufu ti Murtala Muhammed wa ni ilu naa. Ikeja ilu ti Femi Kuti ti wa, ti o si je ilu iya Lagbaja. Ile ise radio bii Eko FM ati Radio Lagos wa ni ilu Ikeja.

Itan ilu yi

Ikeja, eyi ti won n pe ni “Akeja” tele, je ilu ti won fi oruko re lela latari orisa awon Awori ti ilu ota. [2]

Awọn itọkasi