King of Boys: The Return of the King

King of Boys: The Return Of The King jẹ́ fíìmù alápá méje tó jáde ní ọdún 2021,tí Kemi Adetiba jẹ́ olùdarí fún. 27 August 2021 ni wọ́n ṣe àgbéjáde fíìmù yìí[1] lórí Netflix, èyí tó jẹ́ apá kejì King of Boys tó jẹ́ fíìmù adá lórí òṣèlú àti ìwà-ọ̀daràn inú àwùjọ.[2][3] Sola Sobowale àti Toni Tones náà ló ṣe ẹ̀dá ìtàn Eniola Salami pẹ̀lú Reminisce, Illbliss, Akin Lewis, Osas Ighodaro àti Keppy Ekpenyong náà jé ẹ̀dá-ìtàn tí wọ́n ṣe nínú apá kìíní. Àfikún àwọn ẹ̀dá-ìtàn ni Nse Ikpe-Etim, Richard Mofe Damijo, Efa Iwara, Deyemi Okanlawon àti Charly Boy.[2]

King of Boys: The Return of the King
Fáìlì:King of Boys 2.jpg
GenrePolitical crime drama
Created byKemi Adetiba
Directed byKemi Adetiba
StarringSola Sobowale
Toni Tones
Country of originNigeria
Original language(s)English
Igbo
Yoruba
Hausa
No. of seasons1
No. of episodes7
Production
Producer(s)Remi Adetiba
Kemi Adetiba
Joy Nnamdi-Yusuf
Running time60 minutes
Release
Original networkNetflix
Original release27 Oṣù Kẹjọ 2021 (2021-08-27)
Chronology
Related showsKing of Boys

Ìtàn ní ṣókí

Eré náà tẹ̀síwájú lẹ́yìn ìgbé-léhìn-odi ti Eniola Salami, tó sì padà wá lẹ́yìn ọdún márùn-ún. Látàrí àìtẹ́lọ́rùn láti bẹ̀rẹ̀ ìgbé ayé tuntun, ó padà sí ìdí òṣèlú, ti ọ̀tè yìí tún wá le ju tàtẹ̀yìnwá lọ.

Àwọn akópa

  • Sola Sobowale bí i Eniola Salami
  • Toni Tones bí i Young Eniola Salami
  • Reminisce bí i Makanaki
  • Illbliss bí i Odogwu Malay
  • Akin Lewis bí i Aare Akinwande
  • Osas Ighodaro bí i Sade Bello
  • Titi Kuti bí i Ade Tiger
  • Keppy Ekpeyong bí i President Mumusa
  • Nse Ikpe Etim bí i First Lady Jumoke Randle
  • Richard Mofe-Damijo bí i Reverend Ifeanyi
  • Efa Iwara bí i Dapo Banjo
  • Deyemi Okanlawon bí i Adetola Fashina
  • Charly Boy bí i Odudubariba
  • Bimbo Manuel bí i Mr. Mogaji
  • Taiwo Ajai-Lycett bí i Chief Mrs Randle
  • Lord Frank bí i Tunde Randle
  • Lanre Hassan bí i Iyaloja

Àwọn ìtọ́kasí