Manning Marable
William Manning Marable (May 13, 1950 – April 1, 2011)[1] ọ̀mọ̀wé ará Amẹ́ríkà. Marable jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ètò ìgboro, ìtàn àti Àwọn Ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà ní Yunifásítì Kòlúmbíà.[1] Marable ló jẹ́ ọlùdásílẹ̀ àti olùdarí Ilé-ẹ̀kọ́ fún Ìwadìí nínú àwọn Ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.[2] Ó kọ ìwé tó pọ̀, ó sì kópa nínú akitiyan òṣèlú onílọsíwájú. Kí ó tó kú ní ọdún 2011, ó ti parí ìwé-ìgbésíayè lórí Malcolm X tí àkọlẹ́ rẹ̀ únjẹ́ Malcolm X: A Life of Reinvention (2011),[3] èyí tí Marable gba Ẹ̀bùn Pulitzer fún Ìtàn fún ní ọdún 2012 lẹ́yìn tí ọ́ kú.[4]
Manning Marable | |
---|---|
Marable in 2007 | |
Ọjọ́ìbí | William Manning Marable Oṣù Kàrún 13, 1950 Dayton, Ohio, U.S. |
Aláìsí | April 1, 2011 New York City, New York, U.S. | (ọmọ ọdún 60)
Iléẹ̀kọ́ gíga |
|
Olólùfẹ́ | Leith Mullings |
Àwọn Ìtọ́kasí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Pàtàkì:SearchEre idarayaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáIṣẹ́ Àgbẹ̀Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀṣà YorùbáÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÒgún LákáayéWikipedia:Nípa WikipediaWikipediaOwe YorubaAkanlo-edeỌrọ orúkọOrúkọ YorùbáWikipedia:Èbúté ÀwùjọHóséà Ayoola AgboolaÈdè YorùbáPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunWikipedia:Abẹ́ igiÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Wikipedia:Àwọn àyọkà kúkúrúFáwẹ̀lì YorùbáÒrò àyálò YorùbáGbólóhùn YorùbáÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáAṣọHerbert MacaulayMọ́remí ÁjàṣoroṢàngóOmiEwìItan Ijapa ati AjaÀrokòAustrálíàIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Yewa