Microlophus grayii

Microlophus grayii, tí wọ́n mọ̀ sí alángbá Floreana , jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti Floreana[2] Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé Tropidurus tẹ́lẹ̀.[1]

Microlophus grayii
Akọ
Abo
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Chordata
Subphylum:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Squamata
Suborder:
Lacertilia
Infraorder:
Iguania
Ìdílé:
Tropiduridae
Ìbátan:
Irú:
M. grayii
Ìfúnlórúkọ méjì
Microlophus grayii
(Bell, 1843)
Synonyms
  • Leiocephalus grayii Bell, 1843
  • Tropidurus (Craniopeltis) grayii — W. Peters, 1871
  • Leiocephalus grayii
    — Günther, 1877
  • Tropidurus grayi
    — Boulenger, 1885
  • Tropidurus albemarlensis
    Baur, 1890
  • Tropidurus indefatigabilis
    Baur, 1890
  • Tropidurus delanonis Baur, 1890
  • Tropidurus duncanensis
    Baur, 1890
  • Microlophus grayii
    — Frost, 1992 [1]

Ìpinlẹ̀ṣẹ̀

Wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan, grayii, dá John Edward Gray tí ó jẹ́ onímọ̀ ọ̀pọ̀lọ́ àtí afàyàwọ́ lọ́lá.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

Ìwé àkàsíwájú si

  • Bell T. 1843. The Zoology of the Voyage of H.M.S. Beagle Under the Command of Captain Fitzroy, R.N., during the years 1832 to 1836. Edited and Superintended by Charles Darwin ... Naturalist to the Expedition. Part 5. Reptiles. London: Smith, Elder and Company. vi + 51 pp. + Plates 1-20. (Leiocephalus grayii, new species, p. 24 + Plate 14, figure 1). (in English and Latin).
  • Boulenger GA. 1885. Catalogue of the Lizards in the British Museum (Natural History). Second Edition. Volume II. Iguanidæ ... London: Trustees of the British Museum. (Taylor and Francis, printers). xiii + 497 pp. + Plates I-XXIV. (Tropidurus grayi, pp. 172–173).
  • Frost DR. 1992. "Phylogenetic Analysis and Taxonomy of the Tropidurus Group of Lizards (Iguania: Tropiduridae)". American Museum Novitates (3033): 1-68. (Microlophus grayii, p. 48).