Microlophus habelii

Microlophus habelii, tí wọ́n sábà mọ̀ sí alángbá àpáta Marchena  jẹ́ ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti Marchena.[2]

Microlophus habelii
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Chordata
Subphylum:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Squamata
Suborder:
Lacertilia
Infraorder:
Iguania
Ìdílé:
Tropiduridae
Ìbátan:
Irú:
M. habelii
Ìfúnlórúkọ méjì
Microlophus habelii
(Steindachner, 1876)
Àwọn ibi tí a ti lè rí Microlophus habelii ní àwọn erékùṣù Galapagos
Synonyms
  • Tropidurus (Craniopeltis) habelii Steindachner, 1876
  • Tropidurus habelii
    — Van Denburgh & Slevin, 1913
  • Microlophus habelii
    — Frost, 1992
  • Tropidurus pacificus habelii
    — Tiedemann et al., 1994
  • Microlophus habelii
    — Swash & Still, 200[1]

Ìpinlẹ̀ṣẹ̀

Wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan, habelii, dá Simeon Habel, onímọ̀ àdáyébá ọmọ jamaní-Amẹ́ríkà lọ́lá.[3]

ìṣàsọ́tọ̀

Wọ́n fí M. habelii sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kó wọn sí ẹ̀yà Tropidurus, tí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀ tẹ́lẹ̀.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

Ìwé àkàsíwájú si

  • Steindachner F. 1876. "Die Schlangen und Eidechsen der Galapagos-Inseln ". Zoologisch-Botanischen Gesellschaft in Wien 1876: 303-329. (Tropidurus habelii, àwọn ẹ̀yà tuntun). ( Èdè Jẹ́mánì).