Nsukka

Nsukka jẹ́ ìlú kan àti agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ipinle Enugu, ní orílẹ̀-èdè Naijiria. Nsukka pín ààlà ìlú kan náà pẹ̀lú àwọn ìlú bíi: Edem, Opi, Ede-Oballa, àti Obimo.

Nsukka
Àwòrán ìlú Nsukka láti ojú-ìwò orí-òkè kan ní ìlú náàN
Country Nigeria
StateEnugu State
Elevation
1,393 ft (425 m)
Population
 (2007)
 • Total117,086

Ìlú yìí ni University of Nigeria.[1]


Àwọn ìtọ́kasí