Ouagadougou Cathedral

Ouagadougou Cathedral (Faransé: Cathédrale de l'Immaculée-Conception de Ouagadougou) jẹ́ cathedral ti ìjọ Roman Catholic Archdiocese ti Ouagadougou ní Ouagadougou, olú ìlú Burkina Faso. Apostolic vicar Joanny Thévenoud ni ó kọ́ ìjọ náà láàrin àwọn ọdún 1930s, nígbà tí àríwá Áfríkà sì wà lábẹ́ ìdarí orílẹ̀ èdè France,[1] wọ́n sí ilé ìjọsìn náà ní ọjọ́ kàndínlógún oṣù kínní ọdún 1936,[2] lẹ́yìn tí wọ́n fi ọdún méjì kọ.

Cathedral Ouagadougou

Àwọn Ìtọ́kasí