Pepsi

Àdàkọ:Use mdy datesÀdàkọ:Infobox drinkPepsi jẹ́ ọtí ẹlẹ́rì-dòdò tí ilé-iṣẹ́ PepsiCo ṣe. Ọ̀gbẹ́ni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Caleb Bradham ni ó kọ́kọ́ ṣẹ̀dá rẹ̀ lọ́dún 1893, tí ó sìn pè é nígbà náà ní Brad's Drink, lẹ́yìn èyí ni wọ́n yí orúkọ rẹ̀ sí Pepsi-Cola lọ́dún 1898, [1] tí wọ́n wá ń pè é lápèkúrú ní Pepsi lọ́dún 1962.

Ìgo ọtí ẹlẹ́rìndòdò Pepsi, ní ọjà

Àwọn Ìtọ́kasí