Robert Mundell

Robert Alexander Mundell je onimo isiro-okowo to gba Ebun Nobel ninu ọ̀rọ̀-òkòwò. [1]n won bi Mundell ni (born October 24, 1932). O je omo ile Canada, o si je ojogbon ninu imo okowo ni Columbia University ati Chinese University ti ilu Hong Kong.[2]

Robert Alexander Mundell, (1998)

Itokasi