Shakmagia

Shakmagia (Jewelry Box ní èdè Gẹ̀ẹ́sì) jẹ́ ìwé àwòrán Íjíbítì kan.[1][2] Àkọ́lé rẹ̀ tún mọ̀ sí "the Jewelry Box" ní èdè gẹ̀ẹ́sì , ó sì jé àpẹẹrẹ ètọ́ láti sọ tinú ẹni ní Íjíbítì.[3]

CountryEgypt
GenreComic book
PublisherNazra Center for Women's Studies
Publication date
2014

Ọ tún le ka

  • Àtòjọ àwọn ìwé nípa ètọ́ obìnrin

Àwọn Ìtọ́kasí