Stevie Wonder

Stevland Hardaway Judkins (ojoibi May 13, 1950), o yi oruko re si Stevland Hardaway Morris,[1] eni to gbajumo pelu oruko itage re Stevie Wonder, je akorin, alu ilu orin, olootu awo orin ati alakitiyan ara Amerika.[2] O fo loju laipe ti a bi,[3] Wonder towobowe pelu ile-ise Tamla to je ti Motown Records nigba to je omo odun mokanla,[2] o si untesiwaju lati gbe awo orin re jade nibe titi doni.

Stevie Wonder
Stevie Wonder at a conference in Salvador, Brazil in July 2006
Stevie Wonder at a conference in Salvador, Brazil in July 2006
Background information
Orúkọ àbísọStevland Hardaway Judkins
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiStevland Hardaway Morris, Little Stevie Wonder, Eivets Rednow, El Toro Negro
Ìbẹ̀rẹ̀Detroit, Michigan,
United States
Irú orinR&B, pop, soul, funk
Occupation(s)Singer-songwriter, multi-instrumentalist, record producer, activist
InstrumentsVocals, synthesizer, piano, harmonica, drums, bass guitar, congas, bongos, clavinet, melodica, keytar
Years active1961–present
LabelsTamla, Motown Records
Websitehttp://www.steviewonder.net


Itokasi