Abubakar Tafawa Balewa

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Tafawa Balewa)

Abubakar Tafawa Balewa (December 1912 – January 15, 1966) je omo orile ede Nàìjíríà, lati apa ariwa ile Nàìjíríà[1]. Balewa je Alakoso Agba (prime minister) akoko fun ile Nàìjíríà ni Igba Oselu Akoko ile Nàìjíríà leyin igba ti Nàìjíríà gba ominira ni odun 1960.[2] Eni ayesi ni kariaye, o gba owo ni orile Afrika gege bi ikan lara awon ti won daba idasile Akojoegbe Okan ara Afrika (Organization of African Unity, OAU)[3].[4][5]

Abubakar Tafawa Balewa
Alakoso Agba ile Nàìjíríà
In office
October 1, 1959 – January 15, 1966
Arọ́pòNone
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1912
Bauchi, Nàìjíríà
Aláìsí15 January, 1966
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNorthern People's Congress

Igba ewe ati ise-owo

Itokasi