Valdis Zatlers

Valdis Zatlers (ojoibi 22 March 1955) ni Aare orile-ede Latvia keje lowolowo. O bori ninu idiboyan aare 2007 to waye ni 31 May 2007.[1] O bo si ori aga ni 8 July 2007.[2]

Valdis Zatlers
7th President of Latvia
In office
8 July 2007 – 8 July 2011
Alákóso ÀgbàAigars Kalvītis
Ivars Godmanis
Valdis Dombrovskis
AsíwájúVaira Vīķe-Freiberga
Arọ́pòAndris Bērziņš
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kẹta 1955 (1955-03-22) (ọmọ ọdún 69)
Riga, Latvia
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent (Before 2011)
Reform Party (2011–present)
(Àwọn) olólùfẹ́Lilita Zatlere
Àwọn ọmọKārlis
Agnese
Alma materRiga Stradiņš University
Signature


Itokasi