Waaris

Àdàkọ:Use Indian English

Waaris /Àrólé
Fáìlì:Waaris Hindi tv series poster.jpg
Show Poster
Genresinimá aládùn orí tẹlifíṣàn
Created byDevyani Rale
Written byDevyani Rale, Manasvi Sharma, Malvika Asthana, Pranjal Saxena, Nikhil Vaddiboina and Nishikant Roy
Directed byManmeet Singh Sodhi Tabrez khan
Creative director(s)Niraj Kumar Mishra
StarringSee Below
Theme music composerAshish Rego and Saurabh Kalsi
Opening themeWaaris
Country of originIndia
Original language(s)Hindi
No. of seasons1
No. of episodes398
Production
Producer(s)Ashvini Yardi and Devyani Rale
Production location(s)Mumbai, India
Camera setupSingle-camera
Running time20 minutes approx.
Production company(s)Viniyard Films, India
DistributorZee Entertainment Enterprises
Release
Original network&TV
Picture format576i (SDTV)
1080i (HDTV)
Original release16 Oṣù Kàrún 2016 (2016-05-16) – 1 December 2017
External links
Website

Waaris tí ìtumò rẹ̀ lédè Yorùbá jẹ́ Àrólé ni eré sinimá onípele aládùn lédè Hindu láti orílẹ̀ èdè Indian tí wọ́n gbé jáde lọ́dún 2016, tí wọ́n máa ń ṣe àfihàn rẹ̀ lórí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn. Àwọn olórin Nooran Sisters ti kọrin nípa àkọ́lé eré yìí.[1] Gẹ́gẹ́ bí ìṣe àwọn Bacha posh, Olú-ẹ̀dá ìtàn eré yìí, Arti Singh àti Sania Touqueer tí ó tún kópa pàtàkì gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn nínú eré yìí. Àwọn tí wọ́n tún kópa pàtàkì gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn nínú Waaris ni; Anand Suryavanshi, Akshay Dogra, Swati Bajpai

Àwọn Ẹ̀dá-Ìtàn

Àwọn Olú-Ẹ̀dá ìtàn

  • Arti Singh kópa bí Amba Pawaniya
  • Farnaz Shetty kópa bí Manpreet Singh Pawaniya (Preet/Mannu)[2]
  • Neel Motwani kópa bí I Raj Bajwa

Àwọn ẹ̀dá-ìtàn pàtàkì

  • Anand Suryavanshi as Harjeet Singh Bajwa[3]
  • Jasveer Kaur kópa bí Mohini Bajwa[4]
  • Akshay Dogra kópa bí Jagan Singh Pawaniya
  • Farhina Parvez kópa bí Simran Pawaniya (Simmi)
  • Kaivalya Chheda[5] as Sukhveer Pawaniya (Sukkhi)
  • Sanket Choukse kópa bí Rohan Bajwa
  • Ankita Bahugana kópa bí Gunjan Pawaniya
  • Nitin Goswami/Unknown kópa bí Aman Pahuja
  • Swati Bajpai kópa bí Raavi Pawaniya
  • Vandana Lalwani kópa bí Amrit Bajwa
  • Unknown kópa bí Babli Pawaniya
  • Kushabh Manghani kópa bí Nihaal Bajwa
  • Angad Hasija kópa bí Chandar[6]
  • Mohammed Iqbal Khan as Charan Singh Pawaniya (Cameo)[7]
  • Sania Touqueer kópa bí ọmọdé Manpreet Pawaniya (Mannu)
  • Wahib Kapadia kópa bí ọmọdé Raj Bajwa
  • Unknown India kópa bí ọmọdé Rohan Bajwa
  • Yatin Mehta kópa bí Raman Bajwa
  • Unknown as young Gunjan Pawaniya
  • Roop Durgapal/Vindhya Tiwari kópa bí Sakshi
  • Lavina Tandon kópa bí Swaroop Bajwa
  • Mukesh Khanna kópa bí Lala Pratap Singh Bajwa[8][9]
  • Sucheta Shivkumar kópa bí Deena Pawaniya
  • Rahul Verma Rajput kópa bí ọ̀rẹ́ Raj
  • Lakshya Wahi kópa bí Yuvraaj
  • Dolly Bindra kópa bí Dumroo Daayan[10]
  • Pankaj Berry kópa bí Suraiya
  • Gaurav Sharma kópa bí Bheeru Bhairav Singh
  • Bhavana Balsavar kópa bí Sushila
  • Sneh Mirani kópa bí ọmọdé Sukhveer Pawaniya (Sukkhi)
  • Ashish Kapoor kópa bí Jai
  • Eza Sumbul touqeer kópa bí Gunjan

Àwọn Ìtọ́kasí