Wema Sepetu

Wema Sepetu (bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1990) jẹ́ òṣèré lórílẹ̀ èdè Tanzania.[1][2]

Wema Sepetu
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹ̀sán 1990 (1990-09-28) (ọmọ ọdún 33)
Dar es Salaam, Tanzania
Orúkọ mírànSepenga
Iṣẹ́
  • Actress
  • Entrepreneur
Ìgbà iṣẹ́2007–present

Iṣẹ́

Ní ọdún 2011, ó gbé eré Superstar kalẹ̀ tí ó sọ̀rọ̀ nípa ìtàn ìfẹ́ òhun àti Diamond Platnumz[3][4]. Ní ọdún 2014, òun àti Van Vicker jọ gbé eré Day After Death jáde.[5][6] Ní ọdún 2013, ó gbé ilé iṣẹ́ rẹ̀ kalẹ̀ tí ó pè ní Endless Fame Production.[7][8]

Àṣàyàn eré rẹ̀

ỌdúnÀkọ́léIpa tí ó kó
2007A Point of No Return[9]Dina
2008Family Tears[10]Asteria/Joyce Damian
2009Red Valentine[11]Vivian
2010Sakata[12]Beatrice
White Maria[13]Catherine
Tafrani[14]Winnie
201114 Days[15]Irene
Lerato[16]Lerato
Basilisa[17]Natalia
The Diary[18]Queen
DJ Ben[19]Natalie
2012Crazy Tenant[20]Miss Cecilia
House Boy[21]Mama Lulu
It Was Not MeSheila
2014Madame[22]Madame
2015Mapenzi YamerogwaSarah
Saa Mbovu
Chungu Cha TatuDoreen
2016FamilyAileena
2017Kisogo
Heaven Sent[23][24]Samira
2018Day After Death
2019More Than A Woman

Àmì ẹ̀yẹ

ỌdúnAyẹyẹÀmì ẹ̀yẹÈsì
2014Ijumaa Sexiest GirlSexiest GirlGbàá[25]
Swahili Fashion Week AwardsStyle Icon of the YearYàán[26]
2015Tanzania People's Choice AwardsFavorite ActressGbàá[27]
Favorite TV ShowYàán[28]
Nzumari Awards (Kenya)Female Personality of the Year (East Africa)Gbàá[29]
2016Abryanz Style and Fashion AwardsBest Dressed Celebrity (East Africa)Gbàá[30]
2017Swahili Fashion Week AwardsFemale Stylish Personality of the yearGbàá[31]
2018Sinema Zetu International Film FestivalBest ActressGbàá
Best Feature Film (as a producer)Yàán
People's Choice (as a producer)Gbàá
2019Sinema Zetu International Film FestivalBest ActressYàán
Best Feature Film (as a producer)Yàán

Àwọn Ìtọ́kàsi