Ápártáìdì

Ápártáìdì (Geesi:  /əˈpɑːrtd/; Àdàkọ:IPA-af, segregation; lit. "aparthood") ni sistemu ijoba ìṣègbéraga àwọn òyìnbó to da lori iyasotooto eya ti awon oyinbo fi tipatipa fi sejoba ni orile-ede Guusu Afrika ati South West Africa (ti a mo si Namibia loni) lati odun 1948 titi di 1994[note 1] Apartaidi je ijoba tipatipa to da lori baasskap (tabi Ìṣègbéraga àwọn òyìnbó), to mu daju pe awon oyinbo, botile je pe iye won ko po, gaba le ori gbogbo eniyan ni orile-ede Guusu Afrika ninu oselu, awujo ati okowo.[4] Gegebi sistemu awon oyinbo yi se to, awon oyinbo ni won gbudo siwaju ni gbogbo igba, awon omo ara Asia te le won, be sini awon alawodudu ara Afrika lo gbodo gbeyin.[4] The economic legacy and social effects of apartheid continue to the present day.[5][6][7]

Ápártáìdì

Itokasi


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/> tag was found