Gíríìsì

Gíríìsì (English: /ˈɡriːs/  ( listen); Gíríkì: Ελλάδα, Elláda, IPA: [eˈlaða]  ( listen); Èdè Grííkì Ayéijọ́unἙλλάς, Hellás, IPA: [helːás]), bakanna gege bi Hellas ati fun ibise bi Helleniki Olominira (Ελληνική Δημοκρατία, Ellīnikī́ Dīmokratía, IPA: [eliniˈci ðimokraˈtia]),[9] je orile-ede kan ni guusuapailaorun Europe, o budo si apaguusu opin Balkan Peninsula. Griisi ni ile bode mo Albania, Olominira ile Makedonia ati Bulgaria si ariwa, ati Turki si ilaorun. Okun Aegeani dubule si ilaorun re, the Okun Ioniani si iwoorun, ati Okun Mediterraneani si guusu. Griisi ni o ni etiodo kewa togunjulo ni agbaye toje 14,880 km (9,246.00 mi) ni gigun, ti o ni opolopo iye awon erekusu (bi 1400, 227 ni ibi ti aon eniyan ngbe), ninu won ni Crete, Dodecanese, Cyclades, ati awon Erekusu Ioniani. Bi ogorin ninu ogorun ile Griisi ni o je ti awon oke, ninu ibi ti Oke Olympus ni o gajulo to je 2,917 m (9,570.21 ft).

Orílẹ̀-èdè Olómìnira Hẹ́llẹ́nẹ̀
Hellenic Republic

Ελληνική Δημοκρατία
Ellīnikī́ Dīmokratía
Flag of Gíríìsì
Àsìá
Àmì orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Gíríìsì
Àmì orílẹ̀-èdè
Motto: Eleftheria i Thanatos, (Greek: "Ελευθερία ή Θάνατος", "Freedom or Death") (traditional)
Orin ìyìn: Ὕμνος εἰς τὴν Ἐλευθερίαν
Ýmnos eis tīn Eleftherían
Hymn to Liberty1
Ibùdó ilẹ̀  Gíríìsì  (green) – on the European continent  (light green & grey) – in the European Union  (light green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Gíríìsì  (green)

– on the European continent  (light green & grey)
– in the European Union  (light green)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Athens
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaGreek
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
94% Greek,
4% Albanian,
2% others[1][2][3][4]
Orúkọ aráàlúGreek
ÌjọbaParliamentary republic
• Ààrẹ
Katerina Sakellaropoulou (Κατερίνα Σακελλαροπούλου)
• Alákóso Àgbà
Kyriakos Mitsotakis (Κυριάκος Μητσοτάκης)
AṣòfinParliament
Modern statehood
• Independence from the Ottoman Empire
25 March 1821
• Recognized
3 February 1830, in the London Protocol
7 May 1832, in the Convention of London
• Current constitution
11 June 1975,
Third Hellenic Republic
Ìtóbi
• Total
131,990 km2 (50,960 sq mi) (96th)
• Omi (%)
0.8669
Alábùgbé
• 2010 estimate
11,305,118[5] (74th)
• 2011 (preliminary data) census
10,787,690[6]
• Ìdìmọ́ra
85.3/km2 (220.9/sq mi) (88th)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
$318.082 billion[7] (37th)
• Per capita
$28,434[7] (29th)
GDP (nominal)2010 estimate
• Total
$305.415 billion[7] (32nd)
• Per capita
$27,302[7] (29th)
Gini (2005)33[8]
Error: Invalid Gini value
HDI (2011) 0.861
Error: Invalid HDI value · 29th
OwónínáEuro (€)2 (EUR)
Ibi àkókòUTC+2 (EET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+3 (EEST)
Irú ọjọ́ọdúndd/mm/yyyy
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù30
Internet TLD.gr3
  1. Also the national anthem of Cyprus.
  2. Before 2001, the Greek drachma.
  3. The .eu domain is also used, as in other European Union member states.

Griisi oni fa gbongbo de asa-olaju Griisi ayeijoun, nibi ti gbogbo eniyan gba bi ibusun asa-olaju Apaiwoorun. Nitori eyi o je ibi ibere oseluaralu,[10] imoye Apaiwoorun,[11] Awon Idije Olympiki, litireso Apaiwoorun ati itankiko, sayensi oloselu, awon ipile sayensi ati mathematiki pataki, ati drama,[12] ati trajedi ati awada. Asesile yi han gedegbe ninu awon Ibi Oso Agbaye UNESCO 17 ti won wa ni Griisi.

Griisi je orile-ede adagbasoke to ni Human Development Index giga,[13][14][15][16] Griisi ti je omo egbe Isokan Europe lati 1981 ati Isokan Okowo ati Owonina Europe lati 2001,[17] NATO lati 1952,[18] ati Ile-ise Ofurufu Europe lati 2005.[19] Bakanna o tun je omo egbe latibere Isodokan awon Orile-ede, OECD,[20] ati Agbajo Ifowosowopo Okowo ni Okun Dudu. Atensi ni oluilu re; awon ilu pataki miran nibe tun ni Thessaloniki, Patras, Heraklion ati Larissa.

Awon Periferi ati ibile

Fun amojuto, Griisi ni periferi metala ti won je pipin si ibile mokaleladota ([nomoi] error: {{lang}}: text has italic markup (help), singular Gíríkì: nomos). Bakanna ni agbegbe idawa kan wa to n je Oke Athos (Gíríkì: Agio Oros, "Oke Mimo"), to ni bode mo periferi Central Macedonia.

MapNumberPeripheryCapitalArea (km²)Area (sq mi)Population
1AtticaAthens3,8081,4703,761,810
2Central GreeceLamia15,5496,004605,329
3Central MacedoniaThessaloniki18,8117,2631,871,952
4CreteHeraklion8,2593,189601,131
5East Macedonia and ThraceKomotini14,1575,466611,067
6EpirusIoannina9,2033,553353,820
7Ionian IslandsCorfu2,307891212,984
8North AegeanMytilene3,8361,481206,121
9PeloponneseKalamata15,4905,981638,942
10South AegeanErmoupoli5,2862,041302,686
11ThessalyLarissa14,0375,420753,888
12West GreecePatras11,3504,382740,506
13West MacedoniaKozani9,4513,649301,522
-Mount Athos (Autonomous)Karyes3901512,262




Itoka