Ijọidi
(Àtúnjúwe láti Ijoid languages)
Apá gúúsù ilẹ̀ Nigeria ni a ti rí àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí. Èdè náà ni a mọ̀ sí Defaka àti Ijọ. Jenewari àti Williamson (1989) ni wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ isálẹ̀ yìí
Nínú àtẹ yìí, a rí ‘Proto-Ijoid’ tí ó pín sí Defaka ati Ijọ. Ijọ pín Ìlà-oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn. Lábé ìlà-oòrùn ni a ti rí: Nkọrọ, Ibani, Kalabari, Kirike (Okrika), Nembe ati Akaha(Akassa). Lábẹ́ ìwọ̀-oòrùn ni a ti rí : Izon, Biseni, Akita (Okordia), Oruma
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Pàtàkì:SearchEre idarayaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáIṣẹ́ Àgbẹ̀Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀṣà YorùbáÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÒgún LákáayéWikipedia:Nípa WikipediaWikipediaOwe YorubaAkanlo-edeỌrọ orúkọOrúkọ YorùbáWikipedia:Èbúté ÀwùjọHóséà Ayoola AgboolaÈdè YorùbáPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunWikipedia:Abẹ́ igiÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Wikipedia:Àwọn àyọkà kúkúrúFáwẹ̀lì YorùbáÒrò àyálò YorùbáGbólóhùn YorùbáÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáAṣọHerbert MacaulayMọ́remí ÁjàṣoroṢàngóOmiEwìItan Ijapa ati AjaÀrokòAustrálíàIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Yewa