Johann Bernoulli
Johann Bernoulli (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1667, ó sìn di olóògbé ní Ọjọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 1748)[1] jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Swiss onímọ̀ Ìṣirò àti ọ̀kan nínú àwọn onímọ̀ Ìṣirò pàtàkì nínú ẹbí Bernoulli. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ sí kalkulosi ikerelailopin, ó sì kọ́ Leonhard Euler lẹ́kọ̀ọ́ nígbà èwe rẹ̀.[2]
Johann Bernoulli | |
---|---|
Johann Bernoulli | |
Ìbí | Basel, Switzerland | 27 Oṣù Keje 1667
Aláìsí | 1 January 1748 Basel, Switzerland | (ọmọ ọdún 80)
Ibùgbé | Switzerland |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Swiss |
Pápá | Mathematician |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Groningen University of Basel |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Basel |
Doctoral advisor | Jacob Bernoulli |
Doctoral students | Daniel Bernoulli Leonhard Euler Johann Samuel König Pierre Louis Maupertuis |
Ó gbajúmọ̀ fún | Development of infinitesimal calculus Catenary solution Bernoulli's rule Bernoulli's identity |
Religious stance | Calvinist |
Notes Brother of Jakob Bernoulli, and the father of Daniel Bernoulli. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN