Nicolas Cage

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Nicolas Cage (oruko abiso Nicolas Kim Coppola; January 7, 1964)[1][2] je osere, atokun ati oludari filmu ara Amerika to gba Ebun Akademi (Oskar) fun Okunrin Osere Didarajulo Kinni.

Nicolas Cage
Nicolas Cage at the 66th Venice International Film Festival
ÌbíOṣù Kínní 7, 1964 (1964-01-07) (ọmọ ọdún 60)[1]
Long Beach, California, United States
Iṣẹ́Actor
Producer
Director
(Àwọn) ìyàwóPatricia Arquette
(1995–2001)
Lisa Marie Presley
(2002–2004)
Alice Kim
(2004–present)


Itokasi