Rajinikanth
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Indian
Shivaji Rao Gaekwad (bìi ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù kejìlá Ọdún 1950) wọ́n t́n mọ̀ọ́ sí Rajinikanth, jẹ́ òṣère eré ìtàgé Orílẹ èdè Indian tí ó ń ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ fiimu Tamil. Ó ti kópa nínú eré àwon Bollywood, Telugu, Kannada, Malayalam , Hollywood ati eré ìtàgé ní ède Bengali. Ó b`ẹr`ẹ eré ìtàgé ṣíṣe nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ olùdarí ọk`ọ p`ẹlú ilé iṣẹ́ ọk`ọ wíwà Bangalore. Ní ọdún 1973, ó darapọ mọ́ ilé `ẹkọ Madras Film Institute lati gba oyè diploma nínú eré ìtàgé ṣíṣe[1][1][2][3][4]
Rajinikanth | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Shivaji Rao Gaekwad 12 Oṣù Kejìlá 1950 Bangalore, Mysore State, India (now in Karnataka, India) |
Ibùgbé | Chennai, Tamil Nadu, India |
Orílẹ̀-èdè | Indian |
Iṣẹ́ | Film actor, producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1975–present |
Olólùfẹ́ | Latha Rajinikanth (1981–present) |
Àwọn ọmọ |
|
Àwọn olùbátan | see Rajinikanth family tree |
Awards | Padma Vibhushan (2016) Padma Bhushan (2000) |
Àwọn ìtọ́kasí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Pàtàkì:SearchEre idarayaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáIṣẹ́ Àgbẹ̀Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀṣà YorùbáÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÒgún LákáayéWikipedia:Nípa WikipediaWikipediaOwe YorubaAkanlo-edeỌrọ orúkọOrúkọ YorùbáWikipedia:Èbúté ÀwùjọHóséà Ayoola AgboolaÈdè YorùbáPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunWikipedia:Abẹ́ igiÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Wikipedia:Àwọn àyọkà kúkúrúFáwẹ̀lì YorùbáÒrò àyálò YorùbáGbólóhùn YorùbáÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáAṣọHerbert MacaulayMọ́remí ÁjàṣoroṢàngóOmiEwìItan Ijapa ati AjaÀrokòAustrálíàIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Yewa