Sofia Black-D'Elia | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | December 1991 (1991-12) (ọmọ ọdún 32) Clifton, New Jersey, U.S. |
Iṣẹ́ | Òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2009–present |
Sofia Black-D'Elia tí wọ́n bí ní inú oṣù Kejìlá ọdún 1991 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn Tea Marvelli nínú eré Skins, Sage Spence nínú eré Gossip Girl ati Andrea Cornish nínú eré The Night Of. Láàrín ọdún 2017 sí 2018 Black-D'Elia kópa gẹ́gẹ́ bí Sabrina nínú eré FOX àti eré apanilẹ́rìín kan The Mick.
Wọ́n bí Black ní ìlú Clifton, ní agbègbè New Jersey, ní irilẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde girama ní ilé-ẹ̀kọ Clifton High School.[1] Ìyá rẹ̀ Eleanor, ń ṣiṣẹ́ nílé iṣẹ́ ìtẹ̀wé nígbà tí bàbá rẹ̀ Anthony V. D'Elia, jẹ́ adájọ́ ilé-ẹjọ́ gíga jùlọ ní ìlú New Jersey.[2][3][4] Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Italy nígbà tí ìyá rẹ̀ hẹ́ ọmọ ẹ̀yà Jew.[5][6]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ nígbà tí ó ti wà ní ọmọ ọdún márùn ún lásìkò tí ó dara pọ̀ mọ́ ilé-ẹ̀kọ́ tí ó ń kọni ní ijó.[7]
Nígba tí ó di ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún, ó kópa nínú eré onípele ti All My Children gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtan "Bailey". Ní ọdún 2010, ó kópa nínú eré akójọpọ̀ àwọn ògo wẹẹrẹ ilẹ̀ Bríténì nínú eré tí eọ́n pe akọ́lé rẹ̀ ní Skins,[8] Black kópa nínú eré Gossip Girl gẹ́gẹ́ ẹ̀dá ìtàn Sage Spence . Ó tún kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn Jessie nínú eré Michael Bay tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2015.[9] Ní ọdún 2016, Black kópa nínú eré HBO miniseries The Night Of.[10] She played the role of Sabrina Pemberton on The Mick.[11][12][13]
Ìlú New York ni Black-D'Elia fi ṣe ibùgbé.[14]
Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2013 | The Immigrant | Not Magda | |
2014 | Born of War | Mina | |
2015 | Project Almanac | Jessie | |
2016 | Viral | Emma | |
2016 | Ben-Hur | Tirzah |
Ọdún | Àkọ́lé | Ioa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2009–2010 | All My Children | Bailey Wells | 28 episodes |
2011 | Skins | Tea Marvelli | Main role, 10 episodes |
2012 | Gossip Girl | Natasha "Sage" Spence | Recurring role, 9 episodes |
2013 | Betrayal | Jules Whitman | Recurring role, 4 episodes |
2015 | The Messengers | Erin Calder | Main role, 13 episodes |
2016 | The Night Of | Andrea Cornish | Episode: "The Beach" |
2017–2018 | The Mick | Sabrina Pemberton | Main role |
Àdàkọ:TableTBA | Your Honor | Frannie | Main role; upcoming TV series |
Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2011 | Skins Webisodes | Tea Marvelli | Episodes: "Dress Up", "Poker", "The Big Bust Hunt" |
2012 | Somewhere Road | Erika | Short film |
2016 | 10 Crosby | Sofia / Ronnie's Mom | Short film series; segments: "Hi Fi", "Drunk on Youth" |
2016 | Invisible | Tatiana Ashland | Main role, 5 episodes |
Year | Title | Artist | Notes |
---|---|---|---|
2011 | "The Chase Is On" | Hoodie Allen | [15] |
2013 | "If So" | Atlas Genius |
Àdàkọ:Authority control