Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 31 Oṣù Kẹta

Al Gore
Al Gore

Ọjọ́ 31 Oṣù Kẹta:

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

  • 1596 – René Descartes, amoye ara Fransi (al. 1650)
  • 1811 – Robert Bunsen, asiseogun ara Jemani (al. 1899)
  • 1948 – Al Gore (foto), Igbakeji Aare 45k orile-ede Amerika

Àwọn aláìsí lóòní...

  • 1727 – Isaac Newton, asefisiksi ati onimo matimatiki ara Ilegeesi (ib. 1643)
  • 1797 – Olaudah Equiano, asoko-eru omo Igbo (ib.1745)
  • 1980 – Jesse Owens, elere idaraya ara Amerika (ib. 1913)
Ọjọ́ míràn: 2930310102 | ìyókù...