Isaac Newton

Isaac Newton (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù kìíní ọdún 1643 - ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kẹta 1727) jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́nsì ọmọ orílẹ̀-èdè Gẹ̀gẹ̀ẹ́sì. Ó jẹ́ amọ̀ye ninu ẹ̀kọ́ ìsirò, awòràwọ̀, ẹ̀sìn àti ònkòwé. Ní ìgbà ayé rẹ̀, wọ́ń mọ si amọ̀ye ohun gbogbo. Látìnì: Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica, ìwé ti ó kọ ní ọdún 1687 jẹ́ ìpìlẹ̀ fun ìsisẹ́ẹ̀ro ayébáyé (nínu ẹkọ́ọ físíìsì). Ìwé yìí wà nípa òfin ìsirò lóri ìmọ̀ye ìṣẹ̀dá, ó sìm jẹ́ awọn ofin akọ́kọ́.

Sir Isaac Newton
Head and shoulders portrait of man in black with shoulder-length gray hair, a large sharp nose, and an abstracted gaze
Godfrey Kneller's 1689 portrait of Isaac Newton (aged 46)
Ìbí(1643-01-04)4 Oṣù Kínní 1643
[OS: 25 December 1642][1]
Woolsthorpe-by-Colsterworth
Lincolnshire, England
Aláìsí31 March 1727(1727-03-31) (ọmọ ọdún 84)
[OS: 20 March 1727][1]
Kensington, Middlesex, England
IbùgbéEngland
Ará ìlẹ̀English
Ọmọ orílẹ̀-èdèEnglish (British from 1707)
Pápáphysics, mathematics, astronomy, natural philosophy, alchemy, theology
Ilé-ẹ̀kọ́University of Cambridge
Royal Society
Royal Mint
Ibi ẹ̀kọ́Trinity College, Cambridge
Academic advisorsIsaac Barrow[2]
Benjamin Pulleyn[3][4]
Notable studentsRoger Cotes
William Whiston
Ó gbajúmọ̀ fúnNewtonian mechanics
Universal gravitation
Calculus
Optics
InfluencesHenry More[5]
Polish Brethren[6]
InfluencedNicolas Fatio de Duillier
John Keill
Religious stanceArianism; for details see article
Signature
Is. Newton
Notes
His mother was Hannah Ayscough. His half-niece was Catherine Barton.



Itokasi