Will Smith

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Willard Carroll "Will" Smith Jr. (ojoibi September 25, 1968)[2] je osere, olootu, rapper, alawada ati ako-orin ara Amerika. Ni osu April 2007, Newsweek pe ni "osere to lagbarajulo ni Hollywood".[3] Smith ti je yiyan fun Ebun Golden Globe marun ati Ebun Akademi meji, be sini o ti gba Ebun Grammy merin.

Will Smith
Actor Will Smith at the 2017 San Diego Comic-Con International.
Smith at the 2017 San Diego Comic-Con International
Ọjọ́ìbíWillard Carroll Smith Jr.
Oṣù Kẹ̀sán 25, 1968 (1968-09-25) (ọmọ ọdún 55)
Philadelphia, Pennsylvania, U.S.
IbùgbéLos Angeles, California, U.S.
Orúkọ mírànThe Fresh Prince
Iṣẹ́
  • Actor
  • producer
  • rapper
  • songwriter
  • comedian
Ìgbà iṣẹ́1985–present
Net worthÀdàkọ:Gain $250 million (2014)[1]
Olólùfẹ́
  • Sheree Zampino
    (m. 1992; div. 1995)
  • Jada Pinkett
    (m. 1997)
Àwọn ọmọTrey, Jaden, and Willow Smith
Musical career
Irú orinHip hop
Labels
  • Jive/RCA
  • Columbia/SME
  • Interscope/Universal
Associated acts
  • DJ Jazzy Jeff
  • Mary J. Blige
  • Christina Vidal
  • Kenny Greene
  • Tichina Arnold
Websitewillsmith.com
Signature
"3Sw" spells out the signature in the image.


Itokasi