Èdè Bàlóṣì

Ọmọ ẹgbẹ́ èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúṣì. Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tọ́ mílíọ̀nù márùn-ún. Púpọ̀ nínú àwọn tí ó ń sọ ọ́ yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúṣísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlẹ̀ (province) tí ó wà ní apá ìwọ̀-oòrùn jùní pakcstan. Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí ní Baluchistan tó mílíọ̀nù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkọtọ́ Lárúbáwá (Arabic) ni wọ́n fi kọ ọ́ sílẹ̀. Àjọ kan wà tí wọ́n ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkọsílẹ̀ èdè yìí páye. [1] [2]

Balochi
بلوچی baločî
[[File:
|border|200px]]
Sísọ níPakistan, Iran, Afghanistan, Turkmenistan, UAE, Oman
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀7–8 million (1998, Ethnologue) not include Northern Balochi
Èdè ìbátan
Indo-European
  • Indo-Iranian
    • Iranian
      • Western Iranian
        • Northwestern Iranian
          • Balochi
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Àkóso lọ́wọ́Kòsí àkóso oníbiṣẹ́
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-2bal
ISO 639-3variously:
bal – Baluchi (generic)
bgp – Eastern Balochi
bgn – Western Balochi
bcc – Southern Balochi
Indic script
Indic script
This page contains Indic text. Without rendering support you may see irregular vowel positioning and a lack of conjuncts. More...

Àwọn Ìtọ́kasí