Ìhìnrere Márkù

Ìhìnrere Márkù tí àwọn miran ń pè Ihinrere gẹ́gẹ́ bi ti Marku tàbí Marku[1][2] ni ìwé kejì nínú àwọn ìwé mẹ́rin ti ìhìn rere nínú Bíbélì. Ó sọ nípa ìsẹ́ ìránṣẹ́ Jésù láti ìgbà tí a ti ọwọ Jòhánù onitebomi rìí bomi títí di ìgbà tí wọ́n kàn mọ́ àgbélébùú, tí wón sin sí ibojì àti ìgbà tí ibojì rẹ́ ṣófo. Bí ó tilè jé wípé ìhìn rere Marku kò sọ nípa ibí rẹ̀ láti owó Èmi Mímọ́ tàbí ìfarahàn rẹ̀ lẹ́yìn àjíǹde(àwọn ìwé Ìhìn Rere tó kù fi ìdí èyí múlè.[3][4].

The end of Mark 15 (excluding v. 47), along with Mark 16:1 in Codex Sinaiticus (c. AD 350).

Ìhìn rere Marku fi Jésù hàn gẹ́gẹ́ bi Olùkọ́, awonisan, onísẹ́ ìyanu àti ọmọ ènìyàn.[5] Ìhìn rere Marku parí pẹ̀lú sí ṣófo ibojì tí a sin Jesu sí, pẹ̀lú ìlérí láti pàdé ní Galilee, àti sí sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn láti polongo àjíǹde Jesu.[6]

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ onímò ìtàn gbàgbó pé a kò ìhìn rere Marku láàrin 66-74 AD. Ìgbà dí ẹ̀ sáájú tàbí lẹ́yìn tí wọ́n wọ́ tempili kejì ní 70AD.[7].

Àwọn Itokasi