Ìsúlẹ̀ Òòrùn
Ìsúlẹ̀ Òòrùn (solar eclipse) n sele nigbati Òsùpá ba gba arin ile-aye ati oorun koja ti o si di ile-aye loju patapata tabi die lati ri oorun.
Awon Iru Isule Oorun
- Isule patapata (total) n sele nigbati osupa ba di oju oorun patapata.
- Isule oloruka (annular) n sele nigbati osupa ati oorun ba wa ni ori ila kanna ti oorun si han bi oruka.
- Isule ajapo (hybrid) n sele larin isule patapata ati oloruka. Nibikan ni ori ile-aye o han bi isule patapata nibomiran bi isule oloruka. Isule ajapo kii fi be sele.
- Isule eyidie (partial) n sele nigbati osupa ati oorun ko wa ni ori ila kanna, ti osupa si di oorun loju die.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN