Òṣùpá
Òṣùpá (aami: ) jẹ́ olùyípo (satellite) ilẹ̀-Ayé. Arinidaji jíjìnnà sí láti ilẹ̀-ayé títí dé orí òṣùpá jẹ́ kìlómítà 384,403. Ìwọ̀n ìdábùú òbírí yìí fi ìlọ́pò ọgbọ̀n jù ti ilẹ̀-ayé. Ìlà-àárín òṣùpá jẹ́ kìlómítà 3,474 - tó jẹ́ pé díẹ̀ ló fi jù ọ̀kan nínú mẹ́rin lọ sí ti ilẹ̀-ayé. Èyí sì jẹ́ pé kíkún-inú (volume) òṣùpá jẹ́ ìdá àádọ́ta péré ti ilẹ̀-ayé. Fífà ìwúwosí rẹ̀ jẹ́ ìdá mẹ́fà sí ti ilẹ̀-ayé. Òṣùpá ń yípo ilẹ̀-ayé ní ẹ̀ẹ̀kan láàárín ọjọ́ 27.3 (1 oṣù; ọjọ́ mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó lé ní wákàtí mẹ́ta).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN