Òjò
Òjò jẹ́ omi tí ó ń rọ̀ láti sánmọ̀, tí ó ṣì ń di omi ní orí ilẹ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfààní ni omi tí ó ń sọ̀kalẹ̀ yí ń ṣe fún ọmọ ènìyàn, lára rẹ̀ ni a ti ń pèsè iná mọ̀nàmọ́má, ó wúlò nínú ilé, ó wúlò fún mímu, ìdáná àti ìtọ́jú oúnjẹ, ó wúlò fún ìwẹ̀, àti bẹẹ bẹẹ lọ. Síwájú sí, omi òjò tún wúlò fún ìdàgbàsókè àwọn ǹkan ọ̀gbìn wá gbogbo.[1]
Àwọn Ìtókasí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN