Bẹ̀rmúdà

Bermuda (pípè /bɜrˈmjuːdə/; lonibise bi, àwọn Bẹ̀rmúdà tabi Àwọn Erékùṣù Somers) je ile-agbegbe okere Britani ni Ariwa Okun Atlantiki. O budo si ilaorun etiokun awon Ipinle Aparapo, isupoile to sunmo julo ni Cape Hatteras, North Carolina, bi 1,030 kilometres (640 mi) si iwoorun-ariwaiwoorun. O wa bi 1,373 kilometres (853 mi) guusu Halifax, Nova Scotia, Kanada, ati 1,770 kilometres (1,100 mi) ariwailaorun Miami, Florida. Oluilu re ni Hamilton sugbon ibile titobijulo ni ilu Saint George's.

Bẹ̀rmúdà

Motto: "Quo Fata Ferunt"  (Latin)
"Whither the Fates Carry [Us]"
Orin ìyìn: "God Save the Queen" (official)
"Hail to Bermuda" (unofficial)
Location of Bermuda
OlùìlúHamilton
Ìlú Ìbílẹ̀
St. George's
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaGẹ̀ẹ́sì1
Èdè mírànPortuguese1
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
54.8% African-Caribbean
34.1% white
6.4% multiracial
4.3% other
0.4% unspecified[1]
Orúkọ aráàlúBermudian or Bermudan
ÌjọbaÀwọn ilẹ̀ òkèrè Brítánì
• Adobaje
Queen Elizabeth II
• Gomina
Sir Richard Gozney
• Asiwaju
Paula Cox
Ìtóbi
• Total
53.2 km2 (20.5 sq mi) (224th)
• Omi (%)
26%
Alábùgbé
• 2009 estimate
67,837[1] (199th)
• 2000 census
62,059
• Ìdìmọ́ra
1,275/km2 (3,302.2/sq mi) (7th)
GDP (PPP)2007[2] estimate
• Total
$5.85 billion[2] (149th)
• Per capita
$91,477[2] (1st)
HDI (2003)n/a
Error: Invalid HDI value · n/a
OwónínáBermudian dollar2 (BMD)
Ibi àkókòUTC-4 (Atlantic)
Ojúọ̀nà ọkọ́osi
Àmì tẹlifóònù+1-441
ISO 3166 codeBM
Internet TLD.bm
  1. According to CIA World Factbook.
  2. On par with US$.

Bermuda ni ile-agbegbe okere Britani toseku topejulo to si ni olugbe julo, o je bibudo si latowo Ilegeesi ni ogorun odun ki ofin Isoka 1707 to da Ileoba Britani Olokiki aparapo sile. Oluilu Bermuda akoko, St George's, je bibudo sori ni 1612 o si je ilu Ilegeesi ni Amerika topejulo ti awon eniyan ungbe nibe.[3]

Okowo Bermuda dara daada, pelu inawo bi eka okowo re totobijulo, leyin re ni isebewo,[3][4] awon wonyi fun ni GIO tenikookan to gajulo lagbaye ni 2005. O ni ojuojoabeonileoloru .[5]


Itokasi