Bill Gates

William Henry "Bill" Gates III tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1955 (28th/10/1955)[2] jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Amerika, alaanu, oludako ati alaga[3] ilé-iṣẹ́ Microsoft, ilé-iṣẹ́ atolànà kọ̀m̀pútà tó dá sílẹ̀ pẹ̀lú Paul Allen. Gates jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó lọ́wọ́ jùlọ lágbàáyé[4]òun sì ni olówó jùlọ ní àgbáyé lọ́dún 1995, 2009, àyàfi ọdún 2008, nígbà tó bọ́ sí ipò kẹta.[5]Nígbà tó fi ṣíṣe ní Microsoft, Gates wà ní ipò CEO àti amójútó àgbà atolànà kọ̀m̀pútà, bẹ́ẹ̀ sì ni òun ni onípìn-ín ìdákowò tó tóbi jù lọ, ipin ajoni.[6] Ó tún ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé.

Bill Gates
Bill Gates at the World Economic Forum in Davos, 2007
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹ̀wá 28, 1955 (1955-10-28) (ọmọ ọdún 68)
Seattle, Washington, USA
IbùgbéMedina, WA
Orílẹ̀-èdèAmerican
Iléẹ̀kọ́ gígaHarvard University (dropped out in 1975)
Iṣẹ́Chairman of Microsoft (non-executive)
Co-Chair of Bill & Melinda Gates Foundation
Director of Berkshire Hathaway
CEO of Cascade Investment
Net worthÀdàkọ:GainUS$54 billion (2010)[1]
Olólùfẹ́
Melinda Gates (m. 1994)
Àwọn ọmọ3
Parent(s)William H. Gates, Sr.
Mary Maxwell Gates
WebsiteBill Gates
Signature




Àwọn Ìtọ́kasí