Iṣan

Iṣan ni okùn ara tí ó rọ̀ jùlọ tí a lè rí ní ara púpọ̀ nínú ẹranko. Nínú iṣan kọ̀ọ̀kan ni a ti rí protein, actin àtimyosin tí wọ́n gba orín ara wọn kọjá nínú iṣan lọ́hùn ún, àwọn èròjà wọ̀nyí ni wọ́n ń jẹ́ kí iṣan le, rọ̀ tábí kí ó wà láàrin méjì gẹ́gẹ́ bí ipò tí ara bá wà lásìkò kan.

Iṣan
A top-down view of skeletal muscle
Details
SystemMusculoskeletal system
Identifiers
Latinmusculus
TAA04.0.00.000
FMA5022 30316, 5022
Anatomical terminology

Iṣẹ́ iṣan

Láamra iṣẹ́ àwọn iṣan inù ara ni kí ó ràn wá lọ́wọ́ láti lè rìn, gbéra tàbí lọ láti ibìkan sí ibòmíràn lásìkò kan. Iṣan ló ma ń ṣiṣẹ́ ìbójútó ipò ara níbi ìdúró, ìbẹ̀rẹ̀, ìjókòó àti nínà sílẹ̀ gbalaja, tàbí nígbà tí a bá sùn sílẹ̀, iṣan ni ó ń ṣàkóso ìgbòkègbodò àti lílọ bíbọ̀ ara. Ó tún má ń jẹ́ kí àwọn bí ẹ̀jẹ̀ àti omi ó ríbi gbà káàkiri inú ara.[1] Skeletal muscles in turn can be divided into fast and slow twitch fibers.[2][3][4]

Àwọn Ìtọ́ka sí