Jésù
Jésù ará Násárẹ́tì (c. 5 BC/BCE – c. 30 AD/CE[1]), tàbí Jésù Kírísítì tabi Jésù, jẹ́ ẹni tó ṣe kókó jùlọ, yàtọ̀ sí Ọlọ́run nínú Ẹ̀sìn Kírísítì, tí àwọn ẹlẹ́sìn náà gbà gẹ́gẹ́ bí Olùgbàlà Aráyé, èyí tí ó jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀ ni Májẹ̀mú Láéláé nínú Bíbélì, tí gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣin Kíristi tàbí irú wọn gbà pé òun ni Ọmọ Ọlọ́run àti àwòrán Ọlọ́run tí ó jí dìde nínú ipò òkú.[4] Islamu gba Jesu gege bi woli ati Messiah.[5] Ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀sìn mìíràn ni wọ́n tún tẹrí ba fún un lóríṣi ọ̀nà. Jésù jẹ́ ẹnìkan tó ṣe pàtàkì nínú ìtàn ọmọ ènìyàn.
Jésù ará Násárẹ́tì | |
---|---|
6th-century mosaic of Jesus at Basilica of Sant'Apollinare Nuovo in Ravenna. Though depictions of Jesus are culturally important, no undisputed record of what Jesus looked like is known to exist. | |
Ọjọ́ìbí | c. 4 BC/BCE[1] Bethlehem, Judea, Ilẹ̀ọbalúayé Rómù (traditional); Nazareth, Galilee (historical Jesus)[2] |
Aláìsí | c. 30 AD/CE[1] Calvary, Judea, Ilẹ̀ọbalúayé Rómù (According to the New Testament, he rose on the third day after his death.) |
Cause of death | Crucifixion (Historically trusted, important meaning in Christian belief) No cause/death disputed (Islamic belief) |
Resting place | Traditionally and temporarily, a garden tomb located in what is now the Church of the Holy Sepulchre, Jerúsálẹ́mù.[3] |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Ẹ tún le ka
- Ọmọlẹ́yìn (ní Kristẹni)
- Josefu mímọ́
Àwọn Ìtọ́kasí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN