Longan

Taxonomy not available for Dimocarpus; please create it automated assistant

Dimocarpus longan, ti a mo kaakiri gege bi longan ( /ˈlɒŋɑːnˈ/) and dragon's eye, je igi eya ti ohun ogbin re se je.[3] O je okan lara awon igi ebi ọsẹ berry Sapindaceae, ti lychee ati rambutan je okan lara won.[3] Eso longan jọ ti lychee sugbon o yato diẹ lenu .[4] èsó yi wa lati tropical Asia ati China.[5]

Longan
Photograph of a broadly spreading tree
A branch bearing many light brown fruits
Longan fruit
Ipò ìdasí

Data Deficient (IUCN 3.1)[1]
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Template:Taxonomy/DimocarpusD. longan
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/DimocarpusDimocarpus longan
Lour.[2]
Synonyms[2]
  • Dimocarpus undulatus Wight
  • Euphoria cinerea (Turcz.) Radlk.
  • Dimocarpus leichhardtiiS.T. Reynolds
  • Euphoria glabra Blume
  • Euphoria gracilis Radlk.
  • Euphoria leichhardtii Benth.
  • Euphoria longan (Lour.) Steud.
  • Euphoria longana Lam.
  • Euphoria malaiensis (Griff.) Radlk.
  • Euphoria microcarpa Radlk.
  • Euphoria nephelioides Radlk.
  • Euphoria verruculosa Salisb.
  • Nephelium longan (Lour.) Hook.
  • Nephelium longana Cambess.
Àdàkọ:Infobox Chinese/HeaderÀdàkọ:Infobox Chinese/ChineseÀdàkọ:Infobox Chinese/Footer

Longan (from Cantonese lùhng-ngáahn 龍眼, literally 'dragon eye'), je oruko yii nitori pe o jọ ojú inú nigbati a ba sí epo ara rẹ (omo inu dudu maan farahàn bi pupil ati íris ti oju eniyan). Irúgbìn yìí kere ,o ri roboto,o sì lè daradara,o sì tún dudu pelu. Ti eso yìí bá pon,eyin re maan ro,a tun maan duro sinsin,eyi ni o maan mu ki eso yìí se sí boro nipa fifun t'inu rẹ jade bi eni pe a nfo eso sunflower. Nigbati epo re ba ni omi ninu ,ti o sì rọ,eso yìi ko ki se sí. Ríro epo yii le je bákan nitori o le ro nipa Ikore ti ko gbọ tabi tori oríṣi epo ti o je tabi nitori weda tabi nitori ibi ti a kọ wọn si.

Subspecies

Plants of the World Online[6] lists:

  • D. longan var. echinatus Leenhouts (Borneo, Philippines)
  • D. longan var. longetiolatus Leenhouts (Viet Nam)
  • D. longan subsp. malesianus Leenh. (widespread SE Asia)
  • D. longan var. obtusus (Pierre) Leenh. (Indo-China)

Awọn Atokasi